Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 14:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí ẹni tí wọ́n fẹ́ wẹ̀ mọ́ náà fọ aṣọ rẹ̀, kí ó fá irun rẹ̀, kí ó sì wẹ̀, yóo sì di mímọ́. Lẹ́yìn náà, yóo wá sí ibùdó, ṣugbọn ẹ̀yìn àgọ́ rẹ̀ ni yóo máa gbé fún ọjọ́ meje.

Ka pipe ipin Lefitiku 14

Wo Lefitiku 14:8 ni o tọ