Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 14:52 BIBELI MIMỌ (BM)

Bẹ́ẹ̀ ni yóo ṣe fi ẹ̀jẹ̀ ẹyẹ náà ati omi tí ń ṣàn, ati ẹyẹ tí ó wà láàyè, ati igi Kedari, ati ewé hisopu, ati aṣọ pupa tẹ́ẹ́rẹ́ náà sọ ilé náà di mímọ́ pada.

Ka pipe ipin Lefitiku 14

Wo Lefitiku 14:52 ni o tọ