Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 14:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Alufaa yóo pàṣẹ pé kí wọ́n bá ẹni tí wọ́n fẹ́ ṣe ìwẹ̀nùmọ́ fún mú ẹyẹ mímọ́ meji wá ati igi kedari, pẹlu aṣọ pupa tẹ́ẹ́rẹ́ kan, ati ewé hisopu.

Ka pipe ipin Lefitiku 14

Wo Lefitiku 14:4 ni o tọ