Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 14:36 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí alufaa pàṣẹ pé kí wọn kó gbogbo ohun tí ó wà ninu ilé náà jáde, kí ó tó lọ yẹ àrùn náà wò; kí ó má baà pe gbogbo ohun tí ó wà ninu ilé náà ní aláìmọ́; lẹ́yìn náà, kí alufaa lọ wo ilé náà.

Ka pipe ipin Lefitiku 14

Wo Lefitiku 14:36 ni o tọ