Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 14:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Alufaa yóo mú díẹ̀ ninu ẹ̀jẹ̀ ẹran ẹbọ ìmúkúrò ẹ̀bi yìí, yóo fi kan ṣóńṣó etí ọ̀tún, ati àtàǹpàkò ọwọ́ ọ̀tún ati àtàǹpàkò ẹsẹ̀ ọ̀tún ẹni tí wọ́n fẹ́ wẹ̀ mọ́.

Ka pipe ipin Lefitiku 14

Wo Lefitiku 14:14 ni o tọ