Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 13:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn bí ibi tí ó wú náà bá bẹ̀rẹ̀ sí tàn káàkiri ní ara rẹ̀, lẹ́yìn tí ó fi ara rẹ̀ han alufaa fún ìwẹ̀nùmọ́, kí ó tún pada lọ fi ara han alufaa.

Ka pipe ipin Lefitiku 13

Wo Lefitiku 13:7 ni o tọ