Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 13:59 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó jẹ́ òfin tí ó jẹmọ́ àrùn ẹ̀tẹ̀ tí ó bá wà lára ẹ̀wù tabi aṣọ, láti fi mọ̀ bóyá ó mọ́ tabi kò mọ́, kì báà jẹ́ aṣọ onírun tabi olówùú, tabi ohun èlò aláwọ.

Ka pipe ipin Lefitiku 13

Wo Lefitiku 13:59 ni o tọ