Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 13:49 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ibi tí àrùn yìí wà bá bẹ̀rẹ̀ sí í pọ́n tabi, kí ó ní àwọ̀ bíi ti ewéko, kì báà jẹ́ aṣọ olówùú, tabi ti onírun, tabi kí ó jẹ́ awọ tabi ohunkohun tí a fi awọ ṣe, àrùn ẹ̀tẹ̀ ni; dandan ni kí wọ́n fihan alufaa.

Ka pipe ipin Lefitiku 13

Wo Lefitiku 13:49 ni o tọ