Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 13:42 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn bí ibi tí ó pá ní orí rẹ̀ tabi iwájú rẹ̀ yìí bá lé, tí ó sì pọ́n, ẹ̀tẹ̀ ni ó fẹ́ bẹ̀rẹ̀ sí jẹ jáde níbi tí orí tabi iwájú rẹ̀ ti pá.

Ka pipe ipin Lefitiku 13

Wo Lefitiku 13:42 ni o tọ