Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 13:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn bí ọ̀gangan ibẹ̀ bá funfun tí kò sì jìn ju awọ ara rẹ̀ lọ, tí irun ọ̀gangan ibẹ̀ kò sì di funfun, kí alufaa ti abirùn náà mọ́lé fún ọjọ́ meje.

Ka pipe ipin Lefitiku 13

Wo Lefitiku 13:4 ni o tọ