Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 13:30 BIBELI MIMỌ (BM)

kí alufaa yẹ̀ ẹ́ wò, bí ó bá jìn wọnú ju awọ ara lọ, tí irun ọ̀gangan ibẹ̀ bá pọ́n, tí ó sì fẹ́lẹ́, kí alufaa pè é ní aláìmọ́; àrùn ẹ̀yi ni, tíí ṣe àrùn ẹ̀tẹ̀ irun orí tabi ti irùngbọ̀n.

Ka pipe ipin Lefitiku 13

Wo Lefitiku 13:30 ni o tọ