Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 13:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn bí àmì yìí kò bá paradà níbi tí ó wà, tí kò sì tàn káàkiri, àpá oówo lásán ni, kí alufaa pe ẹni náà ní mímọ́.

Ka pipe ipin Lefitiku 13

Wo Lefitiku 13:23 ni o tọ