Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 13:13 BIBELI MIMỌ (BM)

nígbà náà kí alufaa yẹ olúwarẹ̀ wò, bí àrùn ẹ̀tẹ̀ yìí bá ti bo gbogbo ara rẹ̀ patapata, kí ó pè é ní mímọ́. Bí gbogbo ara rẹ̀ patapata bá ti di funfun, ó di mímọ́.

Ka pipe ipin Lefitiku 13

Wo Lefitiku 13:13 ni o tọ