Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 11:46 BIBELI MIMỌ (BM)

Èyí ni òfin tí ó jẹ mọ́ àwọn ẹranko ati ẹyẹ ati àwọn ẹ̀dá alààyè tí wọn wà ninu omi ati àwọn ẹ̀dá alààyè tí wọ́n ń fi àyà fà lórí ilẹ̀,

Ka pipe ipin Lefitiku 11

Wo Lefitiku 11:46 ni o tọ