Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 11:32 BIBELI MIMỌ (BM)

Ohunkohun tí òkú wọn bá jábọ́ lé lórí di aláìmọ́, ìbáà jẹ́ ohun èlò igi, tabi aṣọ tabi awọ, tabi àpò, irú ohun èlò yòówù tí ó lè jẹ́, ó níláti di fífọ̀, yóo sì jẹ́ aláìmọ́ títí di ìrọ̀lẹ́, lẹ́yìn náà, yóo di mímọ́.

Ka pipe ipin Lefitiku 11

Wo Lefitiku 11:32 ni o tọ