Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 11:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Ninu àwọn ẹranko tí wọ́n ń fi ẹsẹ̀ mẹrin rìn, gbogbo àwọn tí wọ́n bá ti ń fi ẹsẹ̀ mẹrẹẹrin rìn tí wọ́n sì ní èékánná jẹ́ aláìmọ́ fun yín; ẹnikẹ́ni tí ó bá fi ọwọ́ kan òkú wọn yóo di aláìmọ́ títí di ìrọ̀lẹ́.

Ka pipe ipin Lefitiku 11

Wo Lefitiku 11:27 ni o tọ