Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 1:3 BIBELI MIMỌ (BM)

“Bí ó bá jẹ́ pé láti inú agbo mààlúù ni ó ti mú un láti fi rú ẹbọ sísun, akọ mààlúù tí kò ní àbààwọ́n ni kí ó mú wá, kí ó mú un wá sí ẹnu ọ̀nà Àgọ́ Àjọ láti fi rúbọ, kí ó lè jẹ́ ìtẹ́wọ́gbà níwájú OLUWA.

Ka pipe ipin Lefitiku 1

Wo Lefitiku 1:3 ni o tọ