Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 1:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn kí ó fi omi fọ nǹkan inú rẹ̀ ati ẹsẹ̀ rẹ̀, kí alufaa fi gbogbo rẹ̀ rúbọ, kí ó sì sun ún lórí pẹpẹ náà. Ẹbọ sísun ni; ẹbọ tí a fi iná sun, tí ó ní òórùn dídùn, tí inú OLUWA dùn sí.

Ka pipe ipin Lefitiku 1

Wo Lefitiku 1:13 ni o tọ