Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Kinni 9:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ìbátan wọn gẹ́gẹ́ bí wọ́n ti tò wọ́n sinu ìwé jẹ́ ẹẹdẹgbẹrun ó lé mẹrindinlọgọta (956). Gbogbo wọn jẹ́ baálé ninu ìdílé wọn, tí ń gbé Jerusalẹmu.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 9

Wo Kronika Kinni 9:9 ni o tọ