Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Kinni 9:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Iṣẹ́ àwọn mìíràn ninu wọn ni láti máa tọ́jú ohun ọ̀ṣọ́ tẹmpili ati ohun èlò mímọ́, ati ìyẹ̀fun ọkà, waini, òróró, turari, ati òjíá.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 9

Wo Kronika Kinni 9:29 ni o tọ