Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Kinni 7:40 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ni ìran Aṣeri, wọ́n jẹ́ baálé baálé ni ìdílé baba wọn, àṣàyàn akọni jagunjagun, ati olórí láàrin àwọn ìjòyè. Àkọsílẹ̀ iye àwọn tí wọ́n tó ogun jà ninu wọn, ní ìdílé ìdílé jẹ́ ẹgbaa mẹtala (26,000).

Ka pipe ipin Kronika Kinni 7

Wo Kronika Kinni 7:40 ni o tọ