Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Kinni 7:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ Tola ni: Usi, Refaaya, Jerieli, Jahimai, Ibisamu ati Ṣemueli, àwọn ni baálé ninu ìdílé Tola, baba wọn, akikanju jagunjagun ni wọ́n ní àkókò wọn. Ní ayé Dafidi ọba, àwọn akikanju jagunjagun wọnyi jẹ́ ẹgbaa mọkanla ó lé ẹgbẹta (22,600).

Ka pipe ipin Kronika Kinni 7

Wo Kronika Kinni 7:2 ni o tọ