Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Kinni 6:68-70 BIBELI MIMỌ (BM)

68. Jokimeamu ati Beti Horoni;

69. Aijaloni ati Gati Rimoni.

70. Ninu ilẹ̀ ìdajì ẹ̀yà Manase tí ó wà ní apá ìwọ̀ oòrùn, wọ́n fún ìdílé àwọn ọmọ Kohati tí ó kù ní Aneri ati Bileamu, pẹlu àwọn pápá oko tí ó yí wọn ká.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 6