Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Kinni 6:42-44 BIBELI MIMỌ (BM)

42. ọmọ Etani, ọmọ Sima, ọmọ Ṣimei,

43. ọmọ Jahati, ọmọ Geriṣomu, ọmọ Lefi.

44. Etani arakunrin wọn láti inú ìdílé Merari ni olórí àwọn ẹgbẹ́ akọrin tí ń dúró ní apá òsì rẹ̀. Ìran Etani títí lọ kan Lefi nìyí: ọmọ Kiṣi ni Etani, ọmọ Abidi, ọmọ Maluki;

Ka pipe ipin Kronika Kinni 6