Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Kinni 6:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Àwọn ọmọ Lefi nìwọ̀nyí: Geṣomu, Kohati ati Merari.

2. Kohati bí ọmọkunrin mẹrin: Amramu, Iṣari, Heburoni ati Usieli.

3. Amramu bí ọmọ mẹta: Aaroni, Mose, ati ọmọbinrin kan tí ń jẹ́ Miriamu.Aaroni bí ọmọkunrin mẹrin: Nadabu, Abihu, Eleasari ati Itamari.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 6