Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Kinni 5:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Reubẹni ni àkọ́bí Jakọbu, (Ṣugbọn nítorí pé Reubẹni fẹ́ ọ̀kan ninu àwọn obinrin baba rẹ̀, baba rẹ̀ gba ipò àgbà lọ́wọ́ rẹ̀, ó sì gbé e fún àwọn ọmọ Josẹfu. Ninu àkọsílẹ̀ ìdílé, a kò kọ orúkọ rẹ̀ sí ipò àkọ́bí.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 5

Wo Kronika Kinni 5:1 ni o tọ