Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Kinni 4:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Àwọn ọmọ Juda ni: Peresi, Hesironi, Kami, Huri, ati Ṣobali.

2. Ṣobali ni ó bí Reaaya. Reaaya sì bí Jahati. Jahati ni baba Ahumai ati Lahadi. Àwọn ni ìdílé àwọn tí ń gbé Sora.

3. Àwọn ọmọ Etamu ni: Jesireeli, Iṣima, ati Idibaṣi. Orúkọ arabinrin wọn ni Haseleliponi.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 4