Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Kinni 3:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ tí Dafidi bí ní Jerusalẹmu nìwọ̀nyí:Batiṣeba, ọmọbinrin Amieli, bí ọmọ mẹrin fún un: Ṣimea, Ṣobabu, Natani ati Solomoni.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 3

Wo Kronika Kinni 3:5 ni o tọ