Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Kinni 29:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Jọ̀wọ́, jẹ́ kí Solomoni ọmọ mi, fi gbogbo ọkàn rẹ̀ pa òfin, àṣẹ ati ìlànà rẹ mọ́, kí ó lè ṣe ohun gbogbo, kí ó sì lè kọ́ tẹmpili tí mo ti múra rẹ̀ sílẹ̀ fún.”

Ka pipe ipin Kronika Kinni 29

Wo Kronika Kinni 29:19 ni o tọ