Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Kinni 29:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun mi, mo mọ̀ pé ò máa yẹ ọkàn wò, o sì ní inú dídùn sí òtítọ́; tọkàntọkàn mi ni mo fi mú gbogbo nǹkan wọnyi wá fún ọ, mo sì ti rí i bí àwọn eniyan rẹ ti fi tọkàntọkàn ati inú dídùn mú ọrẹ wọn wá fún ọ.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 29

Wo Kronika Kinni 29:17 ni o tọ