Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Kinni 28:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo nǹkan wọnyi ni ó kọ sílẹ̀ fínnífínní gẹ́gẹ́ bí ìlànà láti ọ̀dọ̀ OLUWA nípa iṣẹ́ inú tẹmpili; ó ní gbogbo rẹ̀ ni wọ́n sì gbọdọ̀ ṣe gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ̀ náà.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 28

Wo Kronika Kinni 28:19 ni o tọ