Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Kinni 27:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Joabu, ọmọ Seruaya, bẹ̀rẹ̀ sí ka àwọn eniyan, ṣugbọn kò parí rẹ̀. Sibẹsibẹ ibinu OLUWA wá sórí Israẹli nítorí rẹ̀; nítorí náà, kò sí àkọsílẹ̀ fún iye àwọn ọmọ Israẹli ninu ìwé ìtàn ọba Dafidi.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 27

Wo Kronika Kinni 27:24 ni o tọ