Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Kinni 26:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣelomiti yìí ati àwọn arakunrin rẹ̀ ni wọ́n ń bojútó àwọn ẹ̀bùn tí Dafidi ọba, ati ti àwọn olórí àwọn ìdílé, ati èyí tí àwọn olórí ọmọ ogun ẹgbẹẹgbẹrun ati ọgọọgọrun-un, ti yà sọ́tọ̀ fún Ọlọrun.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 26

Wo Kronika Kinni 26:26 ni o tọ