Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Kinni 26:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Gègé mú Ṣupimu ati Hosa fún ẹnu ọ̀nà apá ìwọ̀ oòrùn ati ẹnu ọ̀nà Ṣaleketi, ní ojú ọ̀nà tí ó lọ sí òkè. Olukuluku àwọn aṣọ́nà ni ó ní àkókò iṣẹ́ tirẹ̀.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 26

Wo Kronika Kinni 26:16 ni o tọ