Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Kinni 26:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn aṣọ́nà tẹmpili ni a pín sí ẹgbẹẹgbẹ́ gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn. A pín iṣẹ́ fún àwọn náà gẹ́gẹ́ bí a ti pín iṣẹ́ fún àwọn arakunrin wọn yòókù tí wọ́n ń ṣiṣẹ́ ninu ilé OLUWA.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 26

Wo Kronika Kinni 26:12 ni o tọ