Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Kinni 24:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Pẹlu ìrànlọ́wọ́ Sadoku ọmọ Eleasari ati Ahimeleki ọmọ Itamari, Dafidi pín àwọn ọmọ Aaroni sí ẹgbẹẹgbẹ́ gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ tí wọn ń ṣe ninu iṣẹ́ ìsìn.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 24

Wo Kronika Kinni 24:3 ni o tọ