Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Kinni 23:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ni baálé baálé ninu ìran Lefi, ní ìdílé ìdílé, gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ̀ àwọn tí wọ́n tó ogún ọdún ati jù bẹ́ẹ̀ lọ, tí wọ́n dàgbà tó láti ṣiṣẹ́ ninu ilé OLUWA.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 23

Wo Kronika Kinni 23:24 ni o tọ