Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Kinni 22:9 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ní n óo bí ọmọkunrin kan tí ìjọba rẹ̀ yóo jẹ́ ìjọba alaafia, ó ní òun óo fún un ní alaafia, gbogbo àwọn ọ̀tá rẹ̀ yíká kò sì ní yọ ọ́ lẹ́nu. Solomoni ni orúkọ rẹ̀ yóo máa jẹ́. Ní ìgbà tirẹ̀, Israẹli yóo wà ní alaafia ati àìléwu.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 22

Wo Kronika Kinni 22:9 ni o tọ