Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Kinni 22:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà Dafidi pàṣẹ pé, “Ibí yìí ni ilé OLUWA Ọlọrun, ati pẹpẹ ẹbọ sísun yóo wà fún Israẹli.”

Ka pipe ipin Kronika Kinni 22

Wo Kronika Kinni 22:1 ni o tọ