Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Kinni 21:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Dafidi rí i pé OLUWA ti gbọ́ adura rẹ̀ ní ibi ìpakà Onani ará Jebusi, ó bẹ̀rẹ̀ sí rú àwọn ẹbọ rẹ̀ níbẹ̀.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 21

Wo Kronika Kinni 21:28 ni o tọ