Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Kinni 21:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi tẹ́ pẹpẹ níbẹ̀, ó rú ẹbọ sísun ati ẹbọ alaafia, ó bá képe OLUWA. OLUWA dá a lóhùn: ó rán iná sọ̀kalẹ̀ láti jó ẹbọ sísun náà.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 21

Wo Kronika Kinni 21:26 ni o tọ