Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Kinni 21:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi sọ fún Joabu ati àwọn ọ̀gágun rẹ̀ pé, “Ẹ lọ ka àwọn ọmọ Israẹli láti Beeriṣeba títí dé Dani, kí ẹ wá fún mi lábọ̀, kí n lè mọ iye wọn.”

Ka pipe ipin Kronika Kinni 21

Wo Kronika Kinni 21:2 ni o tọ