Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Kinni 21:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun rán angẹli kan pé kí ó lọ pa Jerusalẹmu run; ṣugbọn bí ó ti fẹ́ pa á run, OLUWA rí i, ó sì yí ọkàn pada, ó wí fún apanirun náà pé, “Ó tó gẹ́ẹ́, dáwọ́ dúró.” Angẹli OLUWA náà bá dúró níbi ìpakà Onani ará Jebusi.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 21

Wo Kronika Kinni 21:15 ni o tọ