Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Kinni 21:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni Dafidi wí fún Gadi pé, “Ìdààmú ńlá dé bá mi, jẹ́ kí n ṣubú sí ọwọ́ Ọlọrun, nítorí àánú rẹ̀ pọ̀; má jẹ́ kí n bọ́ sí ọwọ́ eniyan.”

Ka pipe ipin Kronika Kinni 21

Wo Kronika Kinni 21:13 ni o tọ