Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Kinni 20:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó kó àwọn eniyan tí wọ́n wà ninu ìlú náà, ó sì ń fi wọ́n ṣe oríṣìíríṣìí iṣẹ́: Àwọn kan ń lo ayùn, àwọn kan ń lo ọkọ́, àwọn mìíràn sì ń lo àáké. Bẹ́ẹ̀ ni Dafidi ṣe sí gbogbo àwọn ìlú Amoni. Òun ati àwọn eniyan rẹ̀ bá pada sí Jerusalẹmu.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 20

Wo Kronika Kinni 20:3 ni o tọ