Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Kinni 2:53 BIBELI MIMỌ (BM)

Òun náà ni baba ńlá gbogbo àwọn ìdílé tí ń gbé Kiriati Jearimu, àwọn ìdílé bíi Itiri, Puti, Ṣumati, ati Miṣirai; lára wọn ni àwọn tí wọn ń gbé ìlú Sora ati Eṣitaolu ti ṣẹ̀.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 2

Wo Kronika Kinni 2:53 ni o tọ