Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Kinni 2:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Hesironi di ẹni ọgọta ọdún, ó fẹ́ ọmọbinrin Makiri, baba Gileadi. Ọmọbinrin yìí sì bí ọmọkunrin kan fún un tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Segubu.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 2

Wo Kronika Kinni 2:21 ni o tọ