Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Kinni 17:7 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nítorí náà, sọ fún un pé, èmi OLUWA àwọn ọmọ ogun ní ‘mo mú un wá láti inú pápá, níbi tí ó ti ń da ẹran, pé kí ó wá jọba lórí, àwọn eniyan mi, Israẹli.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 17

Wo Kronika Kinni 17:7 ni o tọ