Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Kinni 17:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi bá lọ jókòó níwájú OLUWA, ó gbadura báyìí pé, “Kí ni èmi ati ilé mi jẹ́, tí o fi gbé mi dé ipò tí mo dé yìí?

Ka pipe ipin Kronika Kinni 17

Wo Kronika Kinni 17:16 ni o tọ