Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Kinni 16:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé ère lásán ni àwọn orílẹ̀-èdè yòókù sọ di ọlọrun,ṣugbọn OLUWA ló dá ọ̀run.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 16

Wo Kronika Kinni 16:26 ni o tọ